UNIQUE FRIENDS SCHOOLSỌkàn sí àwọn èròngbà láti ní ìwé ẹ̀kọ́ tí ó rọrùn láti nyè fún ọmọ ọdún márùn-ún sí mẹ́fà:
A B D E Ẹ
F G GB
Ìgbà II: Àṣà: Oúnjẹ ilẹ̀ wa
Àpẹẹrẹ oúnjẹ ilẹ̀ wa lóríṣiríṣi:
1. Iyán
2. Ẹ̀bà
3. Ìfọ́kọrẹ́
4. Èbìrìpò
5. Ìrẹsì
6. Iṣu
7. Ọ̀jọ̀jọ̀
8. Ègbo
9. Àbàrí 10.
10. Àmàlà
Abbl
Ìgbà III: Lítíréṣọ̀: Ewì kíkà ní èdè Yorùbá
Ewúrẹ́ jẹ́ ẹran ilé
Ewúrẹ jẹ́ ẹran ilé tó maa ń jìyà púpọ̀ nítorí àìgbọràn rẹ̀
Bí wọ́n bá na ewúrẹ́, a gbọn tí méjì pépé
Kó lójú tó ṣe pẹ́, a tun padà síbi tí ó ti jìyà lẹ́ẹ̀kan
Ẹyin ọmọdé ẹ gbọ́, ẹ máa ṣe bí ewúrẹ
Ẹran aláìgọrán
Àwọn èròngbà yìí yọò ṣe ọmọ ẹ̀kọ́ rí ìwé ẹ̀kọ́ tí ó rọrùn, àti nyè fún wọn láti mọ àwọn lẹ́tà alífábẹ́tì, àwọn orúkọ oúnjẹ ilẹ̀ wa, àti ewì ìbọ̀wọ̀fágbà.