UNIQUE FRIENDS SCHOOLSÌgbà I: Èdè: Alifabẹẹti èdè Yorùbá láti p - y
P R S Ṣ T
U W Y
Ìgbà II: Àṣà: Ìwà ọmọlúàbí
Ìwà ọmọlúàbí ni àwọn ìwà tí ó tọ́ tí ó bójú mu tí ènìyàn hù nínú ilé àti láwùjọ.
Àpẹẹrẹ ìwà ọmọlúàbí ni::
1. Òtítọ́ síṣe
2. Ìbọ̀wọ̀ fágbà a
3. Ìteriba
4. Ìgbọràn
5. Ìkíni
Ìgbà III: Lítíréṣọ̀: Orin kikọ
Ọmọ tó mọ ìyá rẹ lójú o
Òsì yó tamọ náà pa
Ọmọ tó mọ ìyá rẹ̀ lójú o
Òṣì yo tamọ náà pa
Ìyá tó jìyà nítorí rẹ
Bàbá tó jìyà nítorí rẹ
Ọmọ tó mọ ìyá rẹ̀ lójú o
Òṣì yo tamọ náà pa