UNIQUE FRIENDS SCHOOLSI: Èdè: Alifabẹẹti láti A dé Y
A B D E Ẹ
F G GB H I
J K L M N
O Ọ P R S
Ṣ T U W Y
Ìgbà II: Àṣà: Ojúṣe ebi/ ìdílé
Bàbá àti ìyá ni àwọn òbí wa. Bàbá ni olórí ẹbí nígbà tí ìyá jẹ́ olùtọ́jú ẹbí. Àwọn ọmọ wà nínú ẹbí láti mú inú àwọn òbí wọn dùn
Nǹkan tí àwọn òbí máa ń pèsè fún ọmọ:
Ìgbà III: Lítíréṣọ̀: Orin kikọ (lórí òbí)
Ìyá lolugbọwọ mi
Tó ń tọ́jú mi
Ní kékéré
Ẹyìn rẹ ló fi ń ponmí
Ìyá kú iṣẹ́ mi
Èmí Kiya mi kú ìṣẹ́
Pẹlú tẹríba mọ́lẹ̀
Emi kò jẹ́kọṣẹ́ funya mí mọ
Ìyá o, ìyá o, ìyá o