UNIQUE FRIENDS SCHOOLSnú: ìgbà i: èdè: oǹkà láti 11-20
11 = Oókànlá
12 = Eéjìlá
13 = Ẹẹ́tàlá
14 = Ẹẹrìnlá
15 = Aárùndínlógún
16 = Ẹẹ́rìnlógún
17 = Ẹẹ́tàdínlógún
18 = Eéjìdínlógún
19 = Oókàndínlógún
20 = ogun
ìgbà ii: Àṣà: Eré ìdárayá
Eré ìdárayá ni àwọn eré tí tèwe tàgba máa ń ṣe láti mú kí ara jí péré. bi àwọn yorùbá ṣe fẹ́ràn iṣẹ́ - síṣe náà ni wọ́n ní àkókò fún eré ìdárayá. eré bojúbojú: àwọn ọmọdé lè tóbi márùndínlogun tàbí jubẹ́ lọ , wọn yóò yan ẹnìkan tí wọn yóò bo ojú rẹ̀, kí o máa ba mọ ibi tí wọn fi ara pamọ́ sí. lẹ́yìn náà wọn yóò maa lé orin, àwọn tí wọn lọ fì ara pamọ́ ni yòó lé orin báyìí: bojúbojú ---------ooooooo olóró ń bọ̀ --------ooooooo ṣé kí n si ---------- máa ti ṣi ẹni tó lórò bá mú -------- òhun ni yòó díjú dípò ti ṣé kí n si ------------- ó yá si
Igbà iii: Lítíréṣọ̀: àlọ́ pípa ní ilẹ̀ yorùbá
Àlọ́ àpamọ̀: bí àpẹẹrẹ:
1. Arẹwà obinrin láàrin egun =ahọ́n
2. kí ló ń kọjá lọ́júde ọba tí kò kọ́ba =àgbàrá
3. Ọ̀pá tínrín kanlẹ̀ ó kan ọ̀run =òjò
4. kí ní ń kan ọba níkoo. = Abẹ
Abbl