UNIQUE FRIENDS SCHOOLSÈdè: Alifabẹẹti láti A dé Y
A B D E Ẹ
F G GB H I
J K L M N
O Ọ P R S
Ṣ T U W Y
Ìgbà II: Àṣà: Ojúṣe ebi/ ìdílé
Bàbá àti ìyá ni àwọn òbí wa
Bàbá ni olórí ẹbí nígbà tí ìyá jẹ́ olùtọ́jú ẹbí tí àwọn ọmọ sí ní láti jíṣẹ́ fún àwọn òbí wọn
Àwọn òbí ní láti pèsè àwọn nǹkan wọ̀nyí fún àwọn ọmọ wọn:
Owó ilé
Abbl
Igbà III: Lítíréṣọ̀: Orin kikọ
Ìyá lolugbọwọ mi
Tó ń tọ́jú mi
Ní kékéré
Ẹyìn rẹ ló fi ń ponmí
Ìyá kú iṣẹ́ mi
Èmí Kiya mi kú ìṣẹ́
Pẹlú tẹríba mọ́lẹ̀
Emi kò jẹ́kọṣẹ́ funya mí mọ
Ìyá o, ìyá o, ìyá o