UNIQUE FRIENDS SCHOOLSEDE: Aroko Atonisona Alapejuwe (YORUBA) - JSS 1
Lesson Topic: Aroko Atonisona Alapejuwe (Expository Essay)
ERONGBA:Ni opin idanileko yii,awon akekoo kookan yoo le so
A)Itumo Aroko Alapejuwe
B) Amuye Aroko Alapejuwe
D)Apeere Aroko Atonisona Alapejuwe
AKORI ISE AROKO ATONISONA ONIROYIN DEETI…………………………..
AKOONU ITUMO
APEERE
ILANA AROKO
Aroko ni ohun ti a ko sile lati inu arojinle wa fun elomiran lati ka. Orisiirisii aroko ni o wa. A ni aroko oniroyin, aroko alapejuwe, aroko alalaye ati bee bee lo. Aroko Oniroyin: Aroko oniroyin ni aroko ti o maa n so itan isele ohun ti a foju ri tabi eyi ti a feti gbo lati enu enikan ti a wa gbe kale fun elomiran lati ka.
Ilana Aroko:
i Yiyan ori oro
ii Ifaara
iii Ipin afo
iv Koko aroko
v Igunle.
IGBELEWON:
IWE AKATILEWA:
1 Oyebamji Mustapha (2009) Eko Ede Yoruba titun iwe kin-in-ni (J S S1 ) University Press oju iwe137-141