UNIQUE FRIENDS SCHOOLSASA
ORI ORO: OGE SISE NILE YORUBA NI AYE ATIJO DEETI……………………….
AKOONU: Aso wiwo
Bata
Koko meta gboogi ni o le wa si ni lo kan nigba ti a ba n soro aso wiwo nile Yoruba. Ekin ni aso ti o wa fun ako (okunrin) tabi abo (obinrin), ekeji ni aso fun orisiirisii igba. Eketa ni aso ti o fi ipo eniyan han.
Irufe aso ti eniyan ba wo ni o toka iru eni ti n se. Aso okunrin ni: agbada, buba, awotele, sokoto sooro pelu fila, dansiki ati kafutaani. Pataki lara aso obinrin ni iro pelu buba, iborun ati gele awon naa ni o ni yeri ati ilabiru. Okunrin lo n wo sokoto ki i se obinrin.
Aso fun orisiirisii igba. Awon aso igba ise ati aso fun igba ayeye. Gberi ni ewu ode, kafo ni sokoto won. Atabeyin ni ti awon agbe. Dandogo, agbada, dansiki pelu fila ni aso igba ayeye.
Ko si eni ti ki i wo bata yala okunrin tabi obinrin. Irufe awon bata ti o wa ni salubata, deja.
IGBELEWON
IWE AKATILEWA