UNIQUE FRIENDS SCHOOLS
APEERE
ILANA AROKO
Aroko ni ohun ti a ko sile lati inu arojinle wa fun elomiran lati ka. Orisiirisii aroko ni o wa. A ni aroko oniroyin, aroko alapejuwe, aroko alalaye ati bee bee lo. Aroko Oniroyin: Aroko oniroyin ni aroko ti o maa n so itan isele ohun ti a foju ri tabi eyi ti a feti gbo lati enu enikan ti a wa gbe kale fun elomiran lati ka. Apeere ori oro aroko oniroyin ni: ojo kan ti n ko le gbagbe, ojo ti mo koko de ogba eranko, ile kan ti o jona ni adugbo mi abbl.
Ilana Aroko:
i Yiyan ori oro
ii Ifaara
iii Ipin afo
iv Koko aroko
v Igunle.
APEERE AROKO ONIROYIN
Aroko oniroyin ni aroko ti o maa n so itan isele ohun ti a foju ri tabi eyi ti a feti gbo lati enu enikan, ti a wa gbe kale bi aworan fun elomiran lati wo/ka Ti a ba n ko aroko, a gbodo lo akoto ode oni. Aroko wa gbodo ni ami ni ori. Apeere aroko oniroyin ni:
i Idije ere onilejile to waye ni ile iwe mi
ii Ojo ibi mi ti o koja.
iii Odun ayeye ibile kan ti o koja.
iv Odun keresimesi ti o koja.
v Irinajo mi si ile okeere.
Idije Ere Boolu Onilejile ti o waye ni ile iwe mi
IGBELEWON
Ko aroko ti ko din ni igba oro (200 words) lori ori oro yii ‘’ija igboro kan ti o waye laarin awon olopaa ati agbero ni ilu Eko’’.
IWE AKATILEWA